top of page

O M O N I Y I

OMONIYI ỌMỌ OLUWO 

 

 

Omoniyi Oluwo

ọmọ ọkọ

ọmọ to ni ìgboyà

Awon kan nbu wipe

Ọlẹ

ọmọ oluwo lasan lasan 

Wiwo la ma wo e mole

Nitori pe awani  egungun, iwo ni ọra

Dapada ! Iro le pa

Ati ọra ati egungun lo wa lara mi

Ko si nkan te le se 

 

 

Meaning

 

Omoniyi son of Oluwo 

Son of his father 

A very brave boy

Some people are abusing him

Calling him lazy man

He calls himself Oluwo for nothing 

We will bring him down 

Because we are the bone and you are the fat

Stop there ! <Omoniyi screams at his abusers>

My body is made of both bones and fat 

There is nothing you can do ! 

 

bottom of page