-2014 DW Award winner-
BLACK INK
ỌMỌTUTU IWALẸWA
Photo Credit: Google Images
ỌMỌTUTU IWALẸWA
Ọmọtutu iwalẹwa
Fun mi ni iwa tutu
Ma je kin dabi olowo aye pẹlú asakasa won
Ti won a ma wo talika bi eni ti o ni ọgbọn lori
Won a ma wipe: Ti o ba ni ọgbọn lori kilode ti o se ni owo?
Won ti gbagbe pe Owo ko ni iwa
Ibeere won si han wipe Owo ko ni ogbon
Ọmọtutu iwalẹwa
Ṣe mi ni ọmọ ti o tutu pelu iwa ti o rẹwa
Meaning
Omotutu Iwalewa ( A Calm Child with a beautiful behaviour)
Please give me a calm behaviour
Do not let me be like the rich of this world that who look at poor people like people who lack knowledge.
Because these rich people often ask : If a poor man is knowledgeable, why isn't he rich?
They have forgotten that money doesn't imply you have a good behaviour
Their question also shows that Money does not mean you have knowledge
Omotutu Iwalewa ( A Calm Child with a beautiful behaviour)
Please make me a calm child with a beautiful heart like yourself.